Ọ̀rọ̀ Kàbìtì: Èèyàn márùn-ún nínú ẹbí Òbílànà dèrò ọ̀dawdle látàrí oúnjẹ tí wọ́n jẹ

A dé ilé àwọn mọ̀lẹ́bí Òbílànà láti bá wọn kẹ́dùn àti láti gbọ́ kúlẹ̀kúlẹ̀ ohun tó ṣẹlẹ̀ gan-an tó mú èèyàn márùn-ún nínú mẹ́fà dèrò ọ̀dawdle alákeji lẹ́yìn oúnjẹ …